Awure itaja


Coming soon on 1st SEPT Ori akuko adie togbo dada ao fi sinu agbada ijo nkan ao ko ewe akoko bomole ao fi odidi atare kan si ao jo ao lo kuna ao da oyin si ao ma fi ika arin ropo ao ma la isoye yi dara otun sise fun awon omo keke tiwan lo ile iwe ao so wipe ki wan ki ika arin bo kiwan la, inu roba ti owo hand lewo la dasi ti ao ti mala OGUN TUDE TOODAJU. Egbo lapa funfun ti ori akitan,,Egbo lapa pupa ti won fi se ogba School ile iwe ,Aso funfun opa kan,opolo aye kan. Egbo lapalapa eyikeyii. Ao ge kekeke si inu ike kan.